sexta-feira, 12 de março de 2010

Convite



ÒRÉ ÀTI ÀBÚRÒ MI

Òwòòwò Pèlú ayó pùpó ni mo fi kó ìpè yìí. Èmi fé wá níbí siré fùn Ogùn, ni Ojó 20 Março 2010, Ejè kí a fi ìpàdé se ìrántí kokànlelogún Ogún. Mú wá Òkùnrin àti obìnrin, Àwon Òmódé àti àgbàlàgbà.
Mo ò oni owó, àmò mo ni ayó àti àlàáfíà.
Èkú àbó.
Ìyálòrìsà Teresa ti’Omulú
Ojò 20/Março/2010 às 21h.
Òwòòwò mo júbà